Lẹyin ti iroyin gbalẹ kan wi pe iṣẹlẹ ijinigbe n waye lera lera lagbegbe Irete atawọn awujọ mii niluu Owerri ni ileeṣẹ ọlọpaa yabo inu igbo Irete nibi ti wọn ti mu awọn ...